Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìfihàn 11:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn sì gbọ́ ohùn ńlá kan láti ọ̀run wá ń wí fún wọn pé, “Ẹ gòkè wá ìhín!” Wọn sì gòkè lọ sí ọ̀run nínú ìkúukúù àwọsánmà; lójú àwọn ọ̀ta wọn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 11

Wo Ìfihàn 11:12 ni o tọ