Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò náàni èmi yóò dojúkọ àwọntí ń ni yín lára,èmi yóò gba atiro là,èmi yóò sì ṣa àwọn tí ó ti fọ́nká jọ,èmi yóò fi ìyìn àti ọlá fún wọn nígbogbo ilẹ̀ tí a bá ti dójútì wọ́n.

Ka pipe ipin Sefanáyà 3

Wo Sefanáyà 3:19 ni o tọ