Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 3:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò náà ni èmi yóò ṣà yín jọ;Nígbà náà ni èmi yóò mú un yín padà wá sílé.Èmi yóò fi ọlá àti ìyìn fún un yínláàárin gbogbo ènìyàn àgbáyé,nígbà tí èmi yóò yí ìgbèkùn yínpadà bọ sípò ní ojú ara yín,”ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Sefanáyà 3

Wo Sefanáyà 3:20 ni o tọ