Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanáyà 3:16-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Ní ọjọ́ náà, wọn yóò sọ fún Jérúsálẹ́mù pé,“Má ṣe bẹ̀rù Síónì;má sì ṣe jẹ́ kí ọwọ́ rẹ kí ó dẹ̀.

17. Olúwa Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ,Ó ní agbára láti gbà ọ là.Yóò yọ̀ ni orí rẹ fún ayọ̀;Yóò tún ọ se nínú ìfẹ́ rẹ̀,Yóò sì fi orin yọ̀ ní orí rẹ.”

18. “Èmi ó kó àwọn tí ó ń banújẹ̀ fún àjọ mímọ́ jọ,àwọn tí ó jẹ́ tirẹ̀;àwọn tí ẹ̀gàn rẹ̀ jásí ẹ̀rù.

Ka pipe ipin Sefanáyà 3