Olúwa Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ,Ó ní agbára láti gbà ọ là.Yóò yọ̀ ni orí rẹ fún ayọ̀;Yóò tún ọ se nínú ìfẹ́ rẹ̀,Yóò sì fi orin yọ̀ ní orí rẹ.”