Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 8:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè, Árónì àti gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì sì ṣe fún àwọn ọmọ Léfì gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti pàṣẹ fún Mósè.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 8

Wo Nọ́ḿbà 8:20 ni o tọ