Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 8:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú Ísírẹ́lì, mo fi àwọn ọmọ Léfì fún Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ẹ̀bùn láti máa ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìpàdé fun àwọn ọmọ Ísírẹ́lì àti láti máa ṣe ètùtù fún wọn kí àjàkálẹ̀-àrùn má ba à kọlu àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nígbà tí wọ́n bá súnmọ́ ibi mímọ́.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 8

Wo Nọ́ḿbà 8:19 ni o tọ