Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọ́ḿbà 8:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Léfì wẹ ara wọn mọ́, wọ́n sì fọ aṣọ wọn. Árónì sì mú wọn wá gẹ́gẹ́ bí ọrẹ fífì níwájú Olúwa, Árónì sì ṣe ètùtù fún wọn láti wẹ̀ wọ́n mọ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 8

Wo Nọ́ḿbà 8:21 ni o tọ