Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 11:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe sọ ara yín di aláìmọ́ nípa èyíkéyí nínú àwọn ohun tí Ọlọ́run dá wọ̀nyí. Ẹ má ṣe sọ ara yín dí àìmọ́ yálà láti ara wọn, tàbí nípaṣẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Léfítíkù 11

Wo Léfítíkù 11:43 ni o tọ