Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 11:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín, ẹ ya ara yín sọ́tọ̀ kí ẹ sì jẹ́ mímọ́ torí pé mo jẹ́ mímọ́. Ẹ má ṣe sọ ara yín di àìmọ́ nípaṣẹ̀ ohunkóhun tí ń rìn kákiri lórí ilẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 11

Wo Léfítíkù 11:44 ni o tọ