Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 51:57 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó sì mú kí àwọn ìjòyè rẹ̀ yó bí ọ̀mùtí,àti àwọn ọlọ́gbọ́n rẹ̀àti àwọn alákòóṣo rẹ̀, àti àwọn akọni rẹ̀,wọn ó sì sun oorun láéláé, wọn kì ó sì jí mọ́,”ní Ọba wí, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Olúwa ọmọ ogun.

Ka pipe ipin Jeremáyà 51

Wo Jeremáyà 51:57 ni o tọ