Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 51:58 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ní Olúwa àwọn ọmọ ogun wí:“Odi Bábílónì gbígbòòrò ní a ó wó lulẹ̀ pátapáta,ẹnu bodè gíga rẹ̀ ní a ó sì fi iná sun:tóbẹ́ẹ̀ tí àwọn ènìyàn ti ṣiṣẹ́ lásán,àti àwọn orílẹ̀-èdè ti ṣiṣẹ́ fún iná,tí àárẹ̀ sì mú wọn.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 51

Wo Jeremáyà 51:58 ni o tọ