Nítorí pé afiniṣe ìjẹ dé sórí rẹ̀,àní sórí Bábílónì;a mú àwọn akọni rẹ̀, a ṣẹ́ gbogbo ọrun wọn:nítorí Ọlọ́run ẹ̀san ni Olúwa,yóò san án nítòótọ́.