Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 34:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sédékáyà Ọba àti àwọn ìjòyè rẹ̀ ní Júdà ni èmí yóò fi lé àwọn ọ̀ta wọn lọ́wọ́, àti àwọn tí ń wá ẹ̀mí wọn àti lé ọwọ́ ogun Bábílónì tí ó ti lọ kúrò lọ́dọ̀ yín.

Ka pipe ipin Jeremáyà 34

Wo Jeremáyà 34:21 ni o tọ