Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 34:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó fi wọ́n lé ọwọ́ àwọn ọ̀ta wọn, àti lé àwọn tí ń wá ẹ̀mí wọn lọ́wọ́. Òkú wọn yóò jẹ́ oúnjẹ fún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run àti fún àwọn ẹranko ìgbẹ́.

Ka pipe ipin Jeremáyà 34

Wo Jeremáyà 34:20 ni o tọ