Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 34:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó èmi ó pàṣẹ ni Olúwa wí, èmi ó sì mú wọn padà sí ìlú yìí, wọn ó sì baà jà, wọn ó sì kóo, wọn ó fi iná jóo. Èmi ó sì sọ ìlú Júdà dí ahoro.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 34

Wo Jeremáyà 34:22 ni o tọ