Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 23:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí,“Ẹmá ṣe fi etí sí àṣọtẹ́lẹ̀ tí àwọn wòlíì èké ń sọ fún un yín.Wọ́n ń kún inú ọkàn yín pẹ̀lú ìrètí asán.Wọ́n ń sọ ìran láti ọkàn ara wọn,kì í ṣe láti ẹnu Olúwa.

Ka pipe ipin Jeremáyà 23

Wo Jeremáyà 23:16 ni o tọ