Jeremáyà 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Nítorí náà, báyìí ni OlúwaỌlọ́run alágbára wí ní ti àwọn wòlíì:“Èmi yóò mú wọn jẹ oúnjẹ kíkorò,wọn yóò mu omi májèlénítorí láti ọ̀dọ̀ àwọn wòlíì Jérúsálẹ́mùni àìwà-bí-Ọlọ́run ti tàn ká gbogbo ilẹ̀.”