Wọ́n ń sọ fún àwọn tí ó ń gàn mí pé,‘Olúwa ti wí pé: Ẹ ó ní àlàáfíà,’Wọ́n sì wí fún gbogbo àwọn tí ó rìn nípa agídí ọkàn rẹ̀ pé,‘Kò sí ìpalára kan tí yóò ṣẹlẹ̀ sí yín.’