Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 19:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísíẹ́lì wí: ‘Tẹ́tí sílẹ̀! Èmi yóò mú ìdààmú tí mo ti sọ àṣọtẹ́lẹ̀ rẹ̀ bá ìlú yìí àti ìgbéríko tí ó yí i ká, nítorí ọlọ́rùn líle ni wọ́n, wọn kò si ní fẹ́ fetí sí ọ̀rọ̀ mi.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 19

Wo Jeremáyà 19:15 ni o tọ