Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 19:14-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Jeremáyà sì padà láti Tófẹ́tì níbi tí Olúwa rán an sí láti sọ àsọtẹ́lẹ̀ ó sì dúró ní gbangba Tẹ́ḿpìlì Olúwa, ó sì sọ fún gbogbo ènìyàn pé,

15. “Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísíẹ́lì wí: ‘Tẹ́tí sílẹ̀! Èmi yóò mú ìdààmú tí mo ti sọ àṣọtẹ́lẹ̀ rẹ̀ bá ìlú yìí àti ìgbéríko tí ó yí i ká, nítorí ọlọ́rùn líle ni wọ́n, wọn kò si ní fẹ́ fetí sí ọ̀rọ̀ mi.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 19