Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 19:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jeremáyà sì padà láti Tófẹ́tì níbi tí Olúwa rán an sí láti sọ àsọtẹ́lẹ̀ ó sì dúró ní gbangba Tẹ́ḿpìlì Olúwa, ó sì sọ fún gbogbo ènìyàn pé,

Ka pipe ipin Jeremáyà 19

Wo Jeremáyà 19:14 ni o tọ