Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo bá lọ sí orílẹ̀ èdè náà,Èmi yóò rí àwọn tí wọ́n fi idà pa.Bí mo bá lọ sí ìlú ńlá,èmi rí àwọn tí ìyàn ti sọ di aláàrùn.Wòlíì àti Àlùfáàti lọ sí ilẹ̀ tí wọn kò mọ̀.’ ”

Ka pipe ipin Jeremáyà 14

Wo Jeremáyà 14:18 ni o tọ