Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 14:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sọ ọ̀rọ̀ yìí fún wọn báyìí pé:“ ‘Jẹ́ kí omijé dà lójú milọ́sàn-án àti lóru láìdúró.Fún wúndíá mi-àwọn ènìyàn mití a dá lọ́gbẹ́ àti lílù bolẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 14

Wo Jeremáyà 14:17 ni o tọ