Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 14:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé o ti kọ Júdà sílẹ̀ pátapáta ni?Ṣé o ti sá Síónì tì?Èéṣe tí o fi pọ́n wa lójútí a kò fi le wò wá sàn?A ń retí àlàáfíàṣùgbọ́n ohun rere kan kò tí ì wá,ní àsìkò ìwòsànìpáyà là ń rí.

Ka pipe ipin Jeremáyà 14

Wo Jeremáyà 14:19 ni o tọ