Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 48:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Agbègbẹ tí o ṣẹ́kù, tí ń ṣe ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ìgbọ̀nwọ́ ni fífẹ̀ àti ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, yóò wà fun àjùmọ̀lò àwọn ará ìlú ńlá náà fún ilé gbígbé àti fún ilẹ̀ ìjẹ fún àwọn ẹran ọ̀sàn. Ìlú ńlá náà yóò wà ní àárin rẹ̀,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:15 ni o tọ