Wọn kò gbọdọ̀ tà tàbí jìrọ̀ ìkankan nínú rẹ̀. Èyí yìí ni ó dára jùlọ lára ilẹ náà, a kò sì gbọdọ̀ fifún ẹlòmíràn nítorí pé ó jẹ́ mímọ́ fún Olúwa.