Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 48:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ̀nyí sì ní bi a ṣe wọ̀n ọ́n: ní ìhà àríwá ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (4,500) ìgbọ̀nwọ́, ni ìhà gúsù ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (4,500) ìgbọ̀nwọ́, ní ìhà ìlà oòrùn ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (4,500) ìgbọ̀nwọ́ àti ní ìhà ìwọ̀ oòrùn ẹgbẹ̀rún mẹ́rin ó lé ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (4,500) ìgbọ̀nwọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:16 ni o tọ