Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 32:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ṣe ibùsùn fún un láàárin àwọn tí a pa, pẹ̀lú gbogbo ìjọ rẹ̀ tí ó yí isà òkú ká. Gbogbo wọn jẹ́ aláìkọlà, tí a fi idà pa. Nítorí pé a tan ẹ̀rù wọn ká ilẹ̀ alààyè, wọn ru ìtìjú wọn pẹ̀lú àwọn tí ó lọ sí ìsàlẹ̀ kòtò; a tẹ́ wọn pẹ̀lú àwọn tí a pa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:25 ni o tọ