Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 32:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Élámù wà níbẹ̀, o yí isà òkú rẹ̀ ká pẹ̀lú gbogbo ijọ rẹ̀. Gbogbo wọn ni a pa, àwọn tí ó ti ipa idà ṣubú. Gbogbo àwọn tí ó ti tan ẹ̀rù ká ilẹ̀ alààyè lọ sí ìsàlẹ̀ láìkọlà sí abẹ́ ilẹ̀. Wọ́n gba ìtìjú wọn pẹ̀lú àwọn tí ó lọ sí ìsàlẹ̀ kòtò.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:24 ni o tọ