Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 32:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Isà òkú wọn wà ní ibi tí ó jìnlẹ̀ gan an nínú kòtò. Gbogbo àwọn tí ó ti tan ẹ̀rù ká ilẹ̀ alààyè ní a pa, tí ó ti ipa idà ṣubú.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:23 ni o tọ