Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 14:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Báwo ni yóò ti burú tó nígbà tí mo bá rán ìdájọ́ kíkan mi mẹ́rin sórí Jérúsálẹ́mù-èyí ni idà àti ìyàn, ẹranko búburú àti àjàkálẹ̀-àrùn-láti pa àwọn ènìyàn àti ẹranko inú rẹ̀!

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:21 ni o tọ