Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 14:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

bo tilẹ̀ jẹ́ pé Nóà, Dáníẹ́lì àti Jóòbù wà nínú rẹ, bí mo ti wà láàyè ni Olúwa Ọlọ́run wí wọn kò le gba ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin wọn lá. Ara wọn nìkan ni ìwà òdodo wọn lè gbà là.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:20 ni o tọ