Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò pọ̀ bíi iyanrìn etí òkun tí a kò le wọ̀n, tí a kò sì le è kà, yóò síṣe. Ní ibi tí wọ́n ti sọ fún wọn pé. ‘Ẹ̀yin kì í ṣe ènìyàn mi,’ níbẹ̀ ni a ó ti máa pè wọ́n ní ‘ọmọ Ọlọ́run alààyè.’

Ka pipe ipin Hósíà 1

Wo Hósíà 1:10 ni o tọ