Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn Júdà àti àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì yóò para pọ̀, wọn yóò sì yan olórí kan tí yóò jáde láti ilẹ̀ náà, nítorí pé ọjọ́ ńlá ni ọjọ́ Jésírẹ́lì yóò jẹ́.

Ka pipe ipin Hósíà 1

Wo Hósíà 1:11 ni o tọ