Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì sọ fún un pé, “Pe orúkọ rẹ̀ ní Lo-ámì, (kì í ṣe ènìyàn mi) nítorí pé ẹ kì í ṣe ènìyàn mi, èmi náà kì í sì í ṣe Ọlọ́run yín.

Ka pipe ipin Hósíà 1

Wo Hósíà 1:9 ni o tọ