Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Hósíà ọmọ Béérì wá ní àkókò ìjọba Ùsáyà, Jótamù, Áhásì àti Heṣekáyà; àwọn ọba Júdà àti ní àkókò ọba Jéróbóámù ọmọ Jóásì ní Ísírẹ́lì:

Ka pipe ipin Hósíà 1

Wo Hósíà 1:1 ni o tọ