Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Olúwa bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ̀rọ̀ láti ẹnu Hósíà, Olúwa wí fún un pé, “Lọ, fẹ́ àgbèrè obìnrin kan fún araa rẹ, kí ó sì bí ọmọ àgbèrè fún ọ nípasẹ̀ àwọn ọkùnrin mìíràn, nítorí ilẹ̀ ti ṣẹ ẹ̀ṣẹ̀ àgbèrè púpọ̀ nípa yíyapa kúrò lọ́dọ̀ Olúwa.”

Ka pipe ipin Hósíà 1

Wo Hósíà 1:2 ni o tọ