Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 7:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì dìde pẹ̀lú ìbínú, ó fi wáìnì sílẹ̀ ó sì jáde lọ sí àgbàlá ààfin. Ṣùgbọ́n nígbà tí Hámánì, ti ríi dájú pé ọba ti pinnu láti pa òun, ó dúró lẹ́yìn láti bẹ Ẹ́sítà ayaba nítorí ẹ̀míi rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 7

Wo Ẹ́sítà 7:7 ni o tọ