Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sítà 7:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọba ṣe padà dé láti àgbàlá ààfin wá sí gbọ̀ngán àsè náà, Hámánì ṣubú sórí àga tí Ẹ́sítà ayaba fẹ̀yìntì.Ọba sì pariwo pé, “Yóò ha tún tẹ́ ayaba níbí yìí, nínú ilé, ní ojú mi bí?”Ní kété tí ọba sọ ọ̀rọ̀ yìí jáde, wọ́n da aṣọ bo Hámánì lójú.

Ka pipe ipin Ẹ́sítà 7

Wo Ẹ́sítà 7:8 ni o tọ