Ésítà sọ wí pé, “alátakò àti ọ̀ta náà ni Hámánì aláìníláárí yìí,”Nígbà náà ni Hámánì wárìrì níwájú ọba àti ayaba.