Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìgbà àwọn baba wá, títí di ìsinsin yìí, àìṣedéédéé wa ti pọ̀ jọjọ. Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa, àwa àti àwọn ọba wa àti àwọn àlùfáà wa ni a ti sọ di ẹni idà àti ìgbèkùn, ìkógun àti ẹni ẹ̀ṣín lọ́wọ́ àwọn àjèjì ọba, bí ó ti rí lónìí.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 9

Wo Ẹ́sírà 9:7 ni o tọ