Ẹ́sírà 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Ṣùgbọ́n ni ìsinsin yìí, fún ìgbà díẹ̀, Olúwa Ọlọ́run ti fi àánú rẹ̀ dá àwa tí ó sẹ́kù sí tí ó sì fún wa ni ibi pàtàkì nínú ibi mímọ́ rẹ̀, nítorí náà Ọlọ́run wa ti fi ìmọ́lẹ̀ fún ojú wa àti ìgbé ayé túntún kúrò nínú ìgbékùn wa.