Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹ́sírà 9:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì gbàdúrà:Ọlọ́run mi, ojú tì mí gidigidi kò sì yá mi lórí láti gbé ojú mi sókè sí ọ, Ọlọ́run mi, nítorí ẹṣẹ̀ wá ga ju orí wa lọ, àwọn àìṣedéédéé wa sì ga kan àwọn ọ̀run.

Ka pipe ipin Ẹ́sírà 9

Wo Ẹ́sírà 9:6 ni o tọ