Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 2:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn àwọn ènìyànkígbe jáde sí Olúwa.Odi ọmọbìnrin Síónì,jẹ́ kí ẹkún rẹ̀ ṣàn bí odòní ọ̀sán àti òru;má ṣe fi ara rẹ fún ìtura,ojú rẹ fún ìsinmi.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2

Wo Ẹkún Jeremáyà 2:18 ni o tọ