Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremáyà 2:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa ti ṣe ohun tí ó pinnu;ó ti mú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ,tí ó sì pàṣẹ ní ọjọ́ pípẹ́.Ó ti sí ọ nípò láì láàánú,ó fún ọ̀tá ní ìsẹ́gun lórí rẹ,ó ti gbé ìwo àwọn ọ̀tá rẹ̀ ga.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2

Wo Ẹkún Jeremáyà 2:17 ni o tọ