Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 8:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rí àgbò náà ó ń kàn sí ìhà ìwọ̀ oòrùn, sí àríwá, àti sí gúsù, kò sí ẹranko kankan tí ó leè dojú kọọ́, kò sí ẹnìkan tí ó leè yọ ọ́ kúrò lọ́wọ́ agbára rẹ̀, ó ń ṣe bí ó ti wù ú, ó sì di alágbára.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8

Wo Dáníẹ́lì 8:4 ni o tọ