Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 8:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí mo ṣe ń ronú nípa èyí, lójijì ni òbúkọ kan tí ó ní ìwo láàrin ojú u rẹ̀ méjèèjì jáde láti ìhà ìwọ̀ oòrùn, ó la gbogbo ayé kọjá láì fi ara kan ilẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8

Wo Dáníẹ́lì 8:5 ni o tọ