Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 8:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wo òkè mo sì rí àgbò kan tí ó ní ìwo méjì níwájú ù mi, ó dúró sí ẹ̀gbẹ́ odò Úláì, àwọn ìwo méjèèje sì gùn. Ṣùgbọ́n ọ̀kan gùn ju èkejì lọ, èyí tí ó gùn jù ni ó yọ jáde kẹ́yìn.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8

Wo Dáníẹ́lì 8:3 ni o tọ