Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí mo ṣe ń wò,“a gbé ìtẹ́ ọba sí ìkàlẹ̀ẹni ìgbàanì orí ìtẹ́ rẹ̀Aṣọ rẹ̀ funfun bí ẹ̀gbọ̀n òwúIrun orí i rẹ̀ funfun bí òwúÌtẹ́ ọba rẹ̀ rí bí ọwọ́ iná.Àwọn kẹ̀kẹ́ rẹ ń jó bí i iná.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:9 ni o tọ